Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b ÀWÒRÁN: (Òkè) Tọkọtaya kan ń gbọ́ ìròyìn lórí tẹlifíṣọ̀n. Nígbà tí ìpàdé parí lọ́jọ́ kan, wọ́n ń sọ èrò tara wọn fáwọn ará kan nípa ohun tí wọ́n wò nínú ìròyìn. (Ìsàlẹ̀) Tọkọtaya kan ń wo ìròyìn látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí kí wọ́n lè mọ ohun tí ètò Ọlọ́run sọ kẹ́yìn nípa àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì. Wọ́n ń fún àwọn èèyàn láwọn ìwé tí ẹrú olóòótọ́ tẹ̀ jáde.