Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tó o bá fẹ́ tẹ̀ síwájú kó o lè ṣèrìbọmi, o gbọ́dọ̀ ní èrò tó tọ́ kó o sì ṣe ohun tó yẹ. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ará Etiópíà kan tó jẹ́ ìjòyè láàfin. A máa rí bí àpẹẹrẹ ẹ̀ ṣe máa ran akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan lọ́wọ́ láti mọ ohun tó yẹ kó ṣe kó lè ṣèrìbọmi.