Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Àgbàyanu làwọn nǹkan tí Jèhófà dá. Ó máa ń yà wá lẹ́nu tá a bá rí àwọn nǹkan tó dá yìí, látorí àwọn nǹkan tó tóbi bí oòrùn títí dórí àwọn nǹkan bíńtín bí ewé kékeré ara òdòdó. A tún lè kẹ́kọ̀ọ́ lára àwọn nǹkan tí Jèhófà dá torí wọ́n máa ń jẹ́ ká mọ irú ẹni tó jẹ́. Nínú àpilẹ̀kọ yìí, a máa sọ̀rọ̀ nípa ìdí tó fi yẹ ká máa kíyè sí àwọn nǹkan tí Jèhófà dá àti bí wọ́n ṣe máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè túbọ̀ sún mọ́ ọn.