Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Àkọsílẹ̀ Ìwé Ìhìn Rere jẹ́ ká mọ̀ pé iṣẹ́ ìyanu tí Jésù ṣe ju ọgbọ̀n (30) lọ. Yàtọ̀ síyẹn, Jésù ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu míì, àmọ́ Bíbélì ò dárúkọ wọn lọ́kọ̀ọ̀kan. Bí àpẹẹrẹ nígbà kan, “gbogbo ìlú” wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ‘ó sì wo ọ̀pọ̀ àwọn tí àìsàn ń yọ lẹ́nu sàn.’—Máàkù 1:32-34.