Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé e ÀWÒRÁN: Jésù là ń wò yẹn tó dúró lẹ́yìn. Ọkọ àti ìyàwó pẹ̀lú àwọn àlejò wọn ń gbádùn wáìnì tó dáa tó ṣe.