Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Jèhófà fi dá wa lójú pé òun máa dáhùn àdúrà wa tó bá bá ìfẹ́ ẹ̀ mu. Tá a bá níṣòro, ó dá wa lójú pé ó máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè jẹ́ olóòótọ́ sí i. Torí náà, ẹ jẹ́ ká sọ̀rọ̀ nípa bí Jèhófà ṣe ń dáhùn àwọn àdúrà wa.