Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c ÀWÒRÁN: Arákùnrin Russell àtàwọn tí wọ́n jọ ń ṣiṣẹ́ lo àwọn ìwé tó ń ṣàlàyé Bíbélì táwọn kan ti ṣe tẹ́lẹ̀.