Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c ÀWÒRÁN: Àwòrán yìí jẹ́ ká rí bí arákùnrin kan ṣe ń kó ìwé lọ fáwọn ará níbi tí wọ́n ti fòfin de iṣẹ́ wa.