Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
d ÀWÒRÁN: Arábìnrin ọ̀dọ́ kan ń kẹ́kọ̀ọ́ lọ́dọ̀ arábìnrin àgbàlagbà kan, kó lè mọ bá á ṣe máa wàásù lórí fóònù; arákùnrin àgbàlagbà kan ń wàásù níbi àtẹ ìwé, ó sì fi hàn pé òun nígboyà; arákùnrin kan tó mọṣẹ́ gan-an ń dá àwọn arákùnrin míì lẹ́kọ̀ọ́ nípa bí wọ́n á ṣe máa tún Ilé Ìpàdé ṣe.