Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Àwọn tó bá fẹ́ ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Ìgbìmọ̀ Tó Ń Ṣètò Ìrànwọ́ Nígbà Àjálù máa kọ́kọ́ gba fọ́ọ̀mù Local Design/Construction Volunteer Application (DC-50) tàbí fọ́ọ̀mù Application for Volunteer Program (A-19), wọ́n á sì ní sùúrù dìgbà tí wọ́n máa pè wọ́n.