Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nínú ayé tí Sátánì ń darí yìí, ọ̀pọ̀ èèyàn ni kì í ní sùúrù. Àmọ́, Bíbélì sọ fún wa pé ká fi sùúrù wọ ara wa láṣọ. Àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ ká rí ìdí tí sùúrù fi ṣe pàtàkì àti bá a ṣe lè túbọ̀ máa ní sùúrù.