Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d Kò sí ẹ̀rí pé àwọn ẹran wọn jẹ mánà torí pé ìwọ̀n tí kálukú wọn máa jẹ ni Jèhófà ní kí wọ́n kó.—Ẹ́kís. 16:15, 16.