Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àpilẹ̀kọ yìí máa jẹ́ kọ́kàn wa balẹ̀ pé Jèhófà máa dáhùn àdúrà wa lọ́nà tó tọ́ torí pé ó nífẹ̀ẹ́ wa.