Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c Ó jọ pé kò sí iṣẹ́ àrà ọ̀tọ̀ kankan tí Jèhófà sọ pé káwọn Násírì máa ṣe kí wọ́n tó lè mú ẹ̀jẹ́ wọn ṣẹ.