Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b ÀLÀYÉ ÀWÒRÁN: Àwòrán yìí jẹ́ ká rí bí lẹ́tà tí Pọ́ọ̀lù kọ sáwọn ará Éfésù nígbà yẹn ṣe rí.