Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé d ÀLÀYÉ ÀWÒRÁN: Arákùnrin kan ń fi àwọn ìlànà Bíbélì tó kọ́ nínú Bíbélì sílò nígbà tó fẹ́ yan eré ìnàjú tó máa wò.