Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ní Àìsáyà 60:1, Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun lo ọ̀rọ̀ náà, “obìnrin” dípò “Síónì,” tàbí “Jerúsálẹ́mù,” torí pé ọ̀rọ̀ ìṣe èdè Hébérù náà, “dìde,” àti “tan ìmọ́lẹ̀” jẹ́ ọ̀rọ̀ tí wọ́n ń lò fún obìnrin, òun ni wọ́n tún pè ní “rẹ” nínú ẹsẹ náà. Ọ̀rọ̀ náà “obìnrin” tí wọ́n lò nínú ẹsẹ yẹn jẹ́ kẹ́ni tó ń kà á mọ̀ pé obìnrin yẹn ń ṣàpẹẹrẹ nǹkan kan.