Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
c Tá a bá fẹ́ “yanjú ọ̀rọ̀” láàárín àwa àti Jèhófà, ó yẹ ká fi hàn pé a ti ronú pìwà dà, ká sọ pé kó dárí jì wá, ká má sì dá ẹ̀ṣẹ̀ náà mọ́. Tá a bá dá ẹ̀ṣẹ̀ ńlá, ó tún yẹ ká lọ bá àwọn alàgbà pé kí wọ́n ràn wá lọ́wọ́.—Jém. 5:14, 15.