Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àwọn Júù máa ń pe Sáàmù 113 sí 118 ní Hálẹ́lì, wọ́n sì máa ń kọ ọ́ kí wọ́n lè fi yin Jèhófà.