Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Tí ọmọ rẹ bá ti kẹ́kọ̀ọ́ ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! tán, ẹ jọ ṣàtúnyẹ̀wò àwọn ẹ̀kọ́ kan ní apá 3 àti 4 tó ṣàlàyé àwọn ìlànà Bíbélì.