Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Omi tí Jésù sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀ ṣàpẹẹrẹ àwọn nǹkan tí Jèhófà ń pèsè ká lè ní ìyè àìnípẹ̀kun.