Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b “Àwọn ohun tó wà ní ọ̀run” tí Pọ́ọ̀lù sọ ní Éfésù 1:10 pé a máa kó jọ yàtọ̀ sí “àwọn àyànfẹ́” tí Jésù sọ ní Mátíù 24:31 àti Máàkù 13:27 pé a máa kó jọ. Ìgbà tí Jèhófà fi ẹ̀mí mímọ́ yan àwọn ẹni àmì òróró ni Pọ́ọ̀lù ń sọ. Àmọ́ ìgbà tá a máa kó àwọn ẹni àmì òróró tó kù láyé lọ sọ́run nígbà ìpọ́njú ńlá ni Jésù ń sọ.