Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé c ÀLÀYÉ ÀWÒRÁN: Àwòrán yìí jẹ́ ká rí iṣẹ́ tí Julia ń ṣe tẹ́lẹ̀ àti bó ṣe ń fayé ẹ̀ sin Jèhófà tọkàntọkàn báyìí.