Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Àìmọye áńgẹ́lì ló wà lọ́run, àmọ́ méjì péré ni Bíbélì dárúkọ, ìyẹn Máíkẹ́lì àti Gébúrẹ́lì.—Dán. 12:1; Lúùkù 1:19.