Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Jésù ló máa ṣáájú nígbà tó bá tó àsìkò láti pa ayé burúkú Sátánì yìí run nígbà ogun Amágẹ́dọ́nì, torí náà ó tọ̀nà tá a bá sọ pé ó ti mọ ọjọ́ tí ogun yẹn máa bẹ̀rẹ̀ àti ìgbà tó máa “parí ìṣẹ́gun rẹ̀.”—Ìfi. 6:2; 19:11-16.