Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Wọ́n tún ń pè é ní Dutch East Indies nígbà yẹn lọ́hùn-ún. Nǹkan bí ọgọ́rùn-ún mẹ́ta [300] ọdún ṣáájú ìgbà yẹn ni àwọn ẹ̀yà Dutch dé síbẹ̀, wọ́n jẹ gàba lé àwọn ará ibẹ̀ lórí, bí wọn ṣe gba òwò àwọn èròjà amóúnjẹ-ta-sánsán mọ́ wọn lọ́wọ́ nìyẹn. Orúkọ tí àwọn ìlú yìí ń jẹ́ lónìí la máa lò jálẹ̀ ìwé yìí.