Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Nígbà tó yá, bàbá Felix àtàwọn àbúrò rẹ̀ mẹ́ta di Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Àbúrò rẹ̀ tó ń jẹ́ Josephine ló fẹ́ André Elias, àwọn méjèèjì sì lọ sí Ilé Ẹ̀kọ́ Gílíádì. Ìtàn ìgbésí ayé Josephine wà nínú Jí! September 2009 lédè Gẹ̀ẹ́sì.