Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ìjà yìí gba gbogbo àgbègbè Maluku fún nǹkan bí ọdún méjì, ó sì mú kí ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn sá kúrò nílé.