Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Wo ìwé atúmọ̀ ọ̀rọ̀ inú Bíbélì náà, New Bible Dictionary, Ìtẹ̀jáde Kẹta, látọwọ́ D. R. W. Wood, ojú ìwé 245; ìwé atúmọ̀ èdè kan tó dá lórí ẹ̀kọ́ ìsìn, ìyẹn Theological Dictionary of the New Testament, Volume VII, ojú ìwé 572; ìwé gbédègbẹ́yọ̀ náà, The International Standard Bible Encyclopedia, Revised Edition, Volume 1, ojú ìwé 825; àti ìwé The Imperial Bible-Dictionary, Volume II, ojú ìwé 84.