Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Wo ìwé atúmọ̀ èdè náà, The Expanded Vine’s Expository Dictionary of New Testament Words, ojú ìwé 1165; ìwé atúmọ̀ èdè kan tí Liddell àti Scott ṣe, tí wọ́n pè ní A Greek-English Lexicon, Ninth Edition, ojú ìwé 1191 sí 1192; àti ìwé Theological Dictionary of the New Testament, Volume V, ojú ìwé 37.