Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Tó o bá ní ìṣòro ìdààmú ọkàn tó le gan-an, ìṣòro àìlè-jẹun dáadáa, ìṣòro kéèyàn máa dá ọgbẹ́ sí ara rẹ̀ lára, tó o bá ń lo ògùn ní ìlòkulò, ìṣòro àìróorun sùn, tó bá ń ṣe ẹ́ bí i pé kó o pa ara rẹ, ohun tó máa dára jù ni pé kó o lọ rí dókítà.