Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ibi gbogbo kọ́ làwọn èèyàn ti máa ń fẹ́ra sọ́nà kí wọ́n tó ṣègbéyàwó, wọ́n máa ń ṣe bẹ́ẹ̀ láwọn ilẹ̀ kan, àmọ́ kì í ṣe àṣà àwọn míì. Bíbélì ò sọ pé dandan ni ká ní àfẹ́sọ́nà, bẹ́ẹ̀ ni kò sọ pé àfi káwọn tó fẹ́ ṣègbéyàwó kọ́kọ́ fẹ́ra wọn sọ́nà.