Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Bí àpẹẹrẹ, àpilẹ̀kọ kan nínú ìwé Marriage & Family Review sọ pé “ìwádìí mẹ́ta tí wọ́n fara balẹ̀ ṣe láàárín àwọn tó ti ṣègbéyàwó tipẹ́, fún nǹkan bíi ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) sí àádọ́ta (50) ọdún ó lé, fi hàn pé ìgbéyàwó àwọn tí wọ́n ń ṣe ẹ̀sìn kan náà, tí ìgbàgbọ́ wọn sì jọra máa ń tọ́jọ́.”—Ìdìpọ̀ 38, àpilẹ̀kọ 1, ojú ìwé 88 (2005).