Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ìwé McClintock àti Strong’s Cyclopedia, Volume IX, ojú ìwé 212, sọ pé: “Ọ̀rọ̀ náà ara olúwa kò sí nínú Májẹ̀mú Tuntun, kò sì síbi tí wọ́n ti lo ọ̀rọ̀ Gíríìkì náà μυστήριον [my·steʹri·on] láti fi tọ́ka sí ìrìbọmi tàbí Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa tàbí ààtò èyíkéyìí míì.”