Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Ọ̀rọ̀ náà “ọ̀run” wá látinú èdè Hébérù tó túmọ̀ sí “gíga” tàbí “gíga jù lọ.” (Òwe 25:3) Wo ìwé The New Brown, Driver, and Briggs Hebrew and English Lexicon of the Old Testament, ojú ìwé 1029.