Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b “Jáà,” tó jẹ́ ìkékúrú orúkọ Ọlọ́run, fara hàn ní nǹkan bí àádọ́ta [50] ìgbà nínú Bíbélì, títí kan bí wọ́n ṣe lò ó nínú ọ̀rọ̀ náà, “Halelúyà,” tàbí “Alelúyà,” tó túmọ̀ sí “Ẹ yin Jáà.”—Ìṣípayá 19:1; Bibeli Ìròyìn Ayọ̀; Bíbélì Mímọ́.