Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Nínú Bíbélì, ọ̀rọ̀ náà, “ẹ̀ṣẹ̀” kò túmọ̀ sí àṣìṣe nìkan, ó tún ń tọ́ka sí ipò àìpé tàbí ẹ̀ṣẹ̀ tá a ti jogún.