Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Kì í ṣe gbogbo nǹkan àràmàǹdà àtàwọn nǹkan tí kò ṣẹlẹ̀ lóòótọ́ tó ń jáde nínú fíìmù ló ń gbé ìbẹ́mìílò lárugẹ. Àmọ́, àwọn Kristẹni tó ti fi Bíbélì kọ́ ẹ̀rí ọkàn wọn máa ń yẹra fún àwọn àṣà àti eré ìnàjú tó ń gbé ìbẹ́mìílò lárugẹ.—2 Kọ́ríńtì 6:17; Hébérù 5:14.