Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
b Ìwé The Expositor’s Bible Commentary sọ nípa Jeremáyà 29:11 pé: “Ìlérí tí Yahweh [Jèhófà] ṣe yìí jẹ́ ọ̀kan lára ìlérí àgbàyanu tó lágbára jù lọ nínú Bíbélì tó jẹ́ ká rí bó ṣe fi ojú àánú hàn sí àwọn tó wà nígbèkùn yìí, àti níkẹyìn, tó jẹ́ kí wọ́n rí ìdí tí wọ́n fi ní láti máa fojú sọ́nà torí pé nǹkan máa tó ṣẹnuure.”—Ìdìpọ̀ 7, ojú ìwé 360