Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Kọ́ńsónáǹtì mẹ́rin náà YHWH ni wọ́n sábà máa ń lò lédè Gẹ̀ẹ́sì, fún lẹ́tà èdè Hébérù mẹ́rin tó jẹ́ orúkọ Ọlọ́run. Àwọn Bíbélì kan lédè Gẹ̀ẹ́sì pè é ní “Yahweh.” Tó o bá fẹ́ àlàyé sí i, wo Àfikún A4 tó ní àkòrí náà “Orúkọ Ọlọ́run Lédè Hébérù” tó wà nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun.