Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Arákùnrin Linck ń sìn ní ẹ̀ka ọ́fíìsì tó wà lórílẹ̀-èdè Kenya, ẹ̀ka yìí ló sì ń bójú tó iṣẹ́ tó ń lọ ní Etiópíà.