Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ẹ̀ka Tó Ń Yàwòrán Ilé Tó sì Ń Kọ́ Ọ ló ń ṣètò bí wọ́n ṣe máa kọ́ Gbọ̀ngàn Ìjọba láwọn ìpínlẹ̀ ìwàásù tí ẹ̀ka ọ́fíìsì kan ń bójú tó. Ẹ̀ka Tó Ń Yàwòrán Ilé Tó sì Ń Kọ́ Ọ Kárí Ayé tó wà lóríléeṣẹ́ wa, ló máa ń pinnu iṣẹ́ tó gba kánjúkánjú kárí ayé, tí wọ́n á sì ṣe kòkáárí bí wọ́n á ṣe kọ́ ọ.