Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé
a Ẹ̀ka Tó Ń Bójú Tó Ilé Ẹ̀kọ́ Ètò Ọlọ́run ló ń ṣètò ohun tí wọ́n ń kọ́ nílé ẹ̀kọ́ yìí, wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ lábẹ́ ìdarí Ìgbìmọ̀ Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ ti Ìgbìmọ̀ Olùdarí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Àwọn tó ń ṣiṣẹ́ ní Ẹ̀ka Tó Ń Bójú Tó Ilé Ẹ̀kọ́ Ètò Ọlọ́run ló máa ń kọ́ni nílé ẹ̀kọ́ yìí, wọ́n tún máa ń pe àwọn míì wá láti wá kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́, bákan náà, àwọn tó wà lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí máa ń kọ́ni nílé ẹ̀kọ́ yìí.