Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé a Torí pé ọwọ́ àti ìrísí ojú làwọn adití fi máa ń sọ̀rọ̀, orí fídíò la máa ń ṣe àwọn ìtẹ̀jáde wọn sí dípò ìwé.