Ìbéèrè 10 (ypq) Ìdáhùn Àwọn Ìbéèrè 10 Táwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí ÌBÉÈRÈ 1 Irú Èèyàn Wo Gan-an Ni Mo Jẹ́? ÌBÉÈRÈ 2 Ṣó Yẹ Kí N Máa Da Ara Mi Láàmú Torí Bí Mo Ṣe Rí? ÌBÉÈRÈ 3 Báwo Ni Mo Ṣe Lè Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀? ÌBÉÈRÈ 4 Kí Ló Yẹ Kí N Ṣe tí Mo Bá Ṣàṣìṣe? ÌBÉÈRÈ 5 Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Mi Níléèwé? ÌBÉÈRÈ 6 Kí Ni Mo Lè Ṣe Káwọn Ojúgbà Mi Má Bàa Ba Ìwà Mi Jẹ́? ÌBÉÈRÈ 7 Kí Ni Mo Lè Ṣe tí Wọ́n Bá Ń Fi Ìbálòpọ̀ Lọ̀ Mí? ÌBÉÈRÈ 8 Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Ìfipá-Báni-Lòpọ̀? ÌBÉÈRÈ 9 Ṣó Yẹ Kí N Gba Ẹ̀kọ́ Ẹfolúṣọ̀n Gbọ́? ÌBÉÈRÈ 10 Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Ràn Mí Lọ́wọ́?