September 1 Kí nìdí tí ìyà fi pọ̀ láyé? Ìgbà wo ló máa dópin? Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí KÓKÓ Ọ̀RỌ̀: KÍ NÌDÍ TÍ ÌYÀ FI PỌ̀ LÁYÉ? ÌGBÀ WO LÓ MÁA DÓPIN? Àìmọye Aláìṣẹ̀ Ló Ti Ṣègbé! Kí Nìdí Tí Ìyà Fi Pọ̀ Tó Báyìí? Ìyà Máa Dópin Láìpẹ́! ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ Tálákà Ni Wá àmọ́ À Ń Fi Ayọ̀ Sin Ọlọ́run Ṣé “Ilé Gogoro Bábélì” Ni Èdè Wa Ti Bẹ̀rẹ̀? SÚN MỌ́ ỌLỌ́RUN “Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Olùfúnni Ọlọ́yàyà” KỌ́ ỌMỌ RẸ Ohun Tí O Bá Ṣe Lè Dun Ọlọ́run—Bí O Ṣe Lè Mú Inú Rẹ̀ Dùn OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ Ohun Tí Bíbélì Sọ