November 1 Ìṣọ̀kan Ayé—Yóò Ha Wáyé Ní Tòótọ́ Láé Bí? Ìṣọ̀kan Ayé—Báwo Ni Yóò Ṣe Wáyé? Àwọn Kristẹni àti Ayé Aráyé Wọ́n Wà Nínú Ayé Ṣùgbọ́n Wọn Kì í Ṣe Apá Kan Rẹ̀ Mo Rí “Ẹni Kékeré Kan” Tí Ó Di “Alágbára Orílẹ̀-èdè” Ṣọ́ra fún ‘Àwọn Epikúréì’ “Fi Àwọn Ohun Ìní Rẹ Tí Ó Níye Lórí Bọlá fún Jèhófà”—Lọ́nà Wo? Àpẹẹrẹ Ìfara-Ẹni-Rúbọ àti Ìdúróṣinṣin Fífa “Omi Jíjìn” Jáde Ìwọ Yóò Ha Fẹ́ Kí A Bẹ̀ Ọ Wò Bí?