No. 3 Ṣé Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ? Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ “Kí Ni Ọlọ́run Ń Wò?” Ṣé Ọlọ́run Ń Kíyè Sí Ẹ? Ṣé Ọ̀rọ̀ Rẹ Yé Ọlọ́run? Ṣé Ọlọ́run Mọ Bí Nǹkan Ṣe Máa Ń Rí Lára Wa? Tẹ́nì Kan Bá Ń Jìyà, Ṣé Ọlọ́run Ló Fà Á? Ta Ló Fà Á? Ọlọ́run Máa Tó Mú Gbogbo Ìyà Kúrò Wàá Jàǹfààní Tó O Bá Mọ̀ Pé Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tó o bá ń jìyà?