June 15 Àwọn Olólùfẹ́ Rẹ tí Wọ́n Ti Kú Níbo Ni Wọ́n Wà? Àwọn Olólùfẹ́ Rẹ tí Wọ́n Ti Kú—Ìwọ Yóò Ha Tún Rí Wọn Bí? Ìwọ Ha Ń Gbádùn Ìdákẹ́kọ̀ọ́ Bí? Gbígbógunti Ìwàmú Ẹ̀sẹ̀ Lórí Ẹran-Ara Ẹlẹ́ṣẹ̀ Sọ Ẹ̀kọ́ Afúnninílera Di Ọ̀nà Ìgbésí-Ayé Rẹ “Ẹja Pípa” Nínú Àwọn Omi Fiji Fífi Ìmọrírì Wo “Ilé Ọlọrun” Abrahamu—A Sin Ín Síhìn-ín, Síbẹ̀ Ó Wàláàyè Kẹ̀? Ìwọ Yóò Ha Fẹ́ Ki A Bẹ̀ Ọ́ Wò Bí?