April 8 Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí “Àwọn Ìlú Ńlá Ń kún Sí I” Kí Ló Fa Ìṣòro—Àwọn Ìlú ńlá? Báwo Lọjọ́ Iwájú Àwọn Ìlú Ńlá Ṣe Máa Rí O? Ǹjẹ́ O Mọ̀? Báwo Ni Màá Ṣe Sọ fún Un Pé Mi Ò Ṣe? Ọ̀nà Tí Wọ́n Ń Gbà Jagun Lóde Òní Ohun Ìjà Kéékèèké, Ìṣòro Ńláńlá Ìrètí Wo Ló Ń bẹ Pé A Óò Kápá Ohun Ìjà? Ṣé Ìsọfúnni Látọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Àlá Jẹ́? Wọ́n Lè Jí Ohun Ìdánimọ̀ Rẹ Lọ! Wíwo Ayé Sísọ Aṣálẹ̀ Di Ilẹ̀ Eléso Àràádọ́ta Ọ̀kẹ́ Yóò Lọ Síbẹ̀—Ṣé Ìwọ Náà Á Lọ?